news

Followers

COMMAND YOUR DAY PRAYER POINTS FOR FRIDAY 31ST MAY, 2024 (+YORUBA EDITION)


BY OLUSEGUN TIMOTHY O.


READ: PSALM 121




1  Lord I thank you for your healing package for me and my family.

  

 2. Doors of favour open for me now in Jesus name.


 3. Angels of God, arise and pursue my divine helpers to me now from wherever they are in Jesus name. 


4  My Father, surround my life with destiny helpers.


5  My God arise and cover those who seek my hurt with reproach and dishonor, in Jesus name.  Amen.


               YORUBA EDITION


1 Oluwa, module lowo Re fun ipese iwosan Re fun emi ati ebi mi


 2  Ẹ̀yin ilẹ̀kùn ojúrere ẹ ṣí fún mi l'órúkọ Jésù.


3 Ẹ̀yin Angeli Ọlọ́run ẹ dìde kí ẹ lé àwọn olùrànlọ́wọ́ àyànmọ́ mi sí mi ní kíákíá láti ibikíbi tí wọn bá wà l'órúkọ Jésù.

 

4 Bàbá mi, yí ayé mi ká pẹ̀lú àwọn olùrànlọ́wọ́ àyànmọ́.


 5 Ọlọ́run mi dide, kí O sì bo gbogbo àwọn tí nwa ìpalára mi, pẹ̀lú ẹ̀gàn àti ẹ̀sín, ní orúkọ Jésù. Amin.



Jesus is Lord, no controversy!



Please Share with others. Thanks!

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts